Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdáàbòbo Ẹ̀tọ́ Àwọn Obìnrin Tí Ó Ń Lo Ìbòrí Se Pàtàkì Láwùjọ- Ẹgbẹ́ Àwọn Obìnrin…

Ẹgbẹ́ Àwọn Obìnrin Mùsùlùmí Obìnrin ti fi ìgbáradì wọn léde lójúnà àti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ àti gbogbo mùtú-mùwà láti dáàbò bo ẹ̀tọ̀ àwọn obìnrin tí ó ń lo ìbòrí   Àjọ náà fí…

FRSC Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Àwọn Akọ̀ròyìn Lórí Àlàkalẹ̀ Òfin Ojú Pópó

Àjọ Ẹ̀ṣọ́ Ojú Pópó ti gbáradì láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ àwọn akọ̀ròyìn láti se ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn akọ̀ròyìn lórí òfin ojú pópó Alákòóso ẹka ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àjọ FRSC, Jonas Agwu ni ó sọ…

Ìtàn Gbogbo Ló Se Pàtàkì Gẹ́gẹ́ Bí Ìlànà Ètò Ìkọ́lé Àtijọ́ Ti Se Kókó Fún…

Mínísítà Fún Ètò Ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀, Mohammed Idris ti pàrọwà sí ẹka tí ó ń mójútó ètò ìkọ́lé láti sé àmójútó ìgbédìde ìtàn tí ó sàfihàn ètò ìkọ́lé ní ayé àtijọ́ fún ìtẹ̀síwájú ìdàgbàsókè…
button