Take a fresh look at your lifestyle.

Àdíkù Yóò Dé Bá Ìgbòkè-gbodò Ní Ìpínlẹ̀ Kano Látàrí Àtúndì Ìbò Tí Yóò…

Àjọ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Kano ti sàlàyé pé àdíkù yóò bá lílọ-bíbọ̀ ní ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fẹ́ẹ̀fà níbi tí ìrètí wà pé àtúndì ìbo yóò wáyé ní ìpínlẹ̀ náà   Kọmísọ́nà àjọ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Kano,…

Àjọ Ọlọ́pàá Sèwádìí Ìsẹ̀lẹ̀ Ìsekúpa Ọba Alayé Kan Ní Ìpínlẹ̀ Kwara

Àjọ Ọlọ́pàá ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí tí ó gbépọn lórí ìsẹ̀lẹ̀ ìsekúpa Olukoro ti ilẹ̀ Ikoro, Ọba Peter Ṣegun Aremu-Cole ní ìjọba ìbílẹ̀ Ekiti, Ìpínlẹ̀ Kwara, níbi tí wọ́n ti jí ayaba àti àwọn ènìyàn méjì míràn gbé…
button