Ẹ Lọ Ọ Fọkàn Balẹ̀: Shinkafi Pàrọwà Sí Àwọn Alátìlẹyìn Rẹ̀ Látàrí Àbájáde Èsì…
Ògúnná gbòngbò kan nínú ẹgbẹ́ òsèlú APC, Ọ̀mọ̀wé Sani Shinkafi ti pàrọwà sí àwọn ènìyàn ẹkùn Shinkafi, ìpínlẹ̀ Zamfara láti fọkàn balẹ̀ látàrí àbájáde èsì ìdìbò tí ó wáyé ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ní…