Take a fresh look at your lifestyle.

Látàrí Rúkè-rúdò Tí Ó Wáyé Lásìkò Eré Ìdárayá : Àjọ NPFL Jẹ Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù…

Àjọ Alákòso  Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Abẹ́lé ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti jẹ Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù El-Kanemi níyà látàrí bí wọ́n se kùnà láti se ètò tí ó múná dóko lásìkò ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí ó wáyé láàrin ẹgbẹ́…

Ohun Àmúyẹ Ni Iná Agbára Òòrùn Oní Bílíọ̀nù Mẹ́wàá Fún Ọ́ọ́fìsì Ààrẹ Jẹ́-…

Olùbádámọ̀ràn pàtàkì sí Ààrẹ lórí Ìfọ̀rọ̀léde, ọ̀gbẹ́ni Bayọ Ọnanuga ti sàlàyé bíbuwọ́lu bílíọ̀nù mẹ́wàá fún iná agbára òòrùn èyí tí ó wà fún ilé iṣẹ́ Ààrẹ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó tọ́, tí ó sì wà…

Ìpínlẹ̀ Kaduna Fi Òpin Sí Kárà-kátà Àwọn Ilé Tí Ó Wà Nínú Ọgbà Ilé Ìwé Ìjọba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kaduna ti fi òpin sí kárà-kátà àwọn ilé tí ó wà nínú àwọn ilé ìwé ìjọba papàá jùlọ Ilé Ìwé Queen Amina, Alhuda àti Ilé Ìwé Ẹ̀kọ́ Ìsòwò   Akọ̀wé ìjọba Ìpínlẹ̀ Kaduna, Abdulkadir…

Gómìnà Ráddà Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Se Àtìlẹyìn Fún Ẹka Ètò Àṣà Àti Ohun Ìsẹ̀m̀báyé

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina, Ọ̀mọ̀wé Dikko Radda ti jẹ́jẹ̀ẹ́ àtìlẹyìn rẹ̀ fún ẹka ètò Àṣà, Ìgbafẹ́ àti Ohun Ìsẹ̀m̀báyé látàrí pàtàkì Àṣà àti pípa àwọn ohun àtijọ́ mọ́   Gómìnà Radda jẹ́ ẹ̀jẹ́ náà…

Látàrí Ìsẹ̀lẹ̀ Láabi Tí Ó Wáyé Ní Ìlú Billiri Lásìkò Àjíǹde, Gómìnà Pe Ìpàdé…

Gómìnà Muhammadu Inuwa ti Ìpínlẹ̀ Gombe ti pe ìpàdé pàjáwìrì fún ètò àbò láti wá ojútùú sí ìsẹ̀lẹ̀ láabi tí ó wáyé ní ìlú Billiri lásìkò Àjíǹde níbi tí àwọn ènìyàn ti pàdánù ẹ̀mí tí àwọn…
button