Orílẹ̀-èdè Algeria Se Ìfilọ́lẹ̀ Mọ́sálásí Tí Ó Tóbi Jùlọ Ní Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Lẹ́yìn…
Algeria se ìfilọ́lẹ̀ Mọ́sálásí ńlá kan èyí tí ó wáyé lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpènijà
Àwọn agbaṣẹ́se Orílẹ̀-èdè China ni ìròyìn fi yéwa pé ó se iṣẹ́ náà. Mọ́sálásí Algeria náà ni ó jẹ́ èyí tí òsóóró…