Ènìyàn Méjìlélógún Wà Ní Àtìmọ́lé Látàrí Ìsẹ̀lẹ̀ Àdó Olóró Ní Orílẹ̀ Èdè…
Àjọ ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Turkey ti àwọn afurasí méjìlélógún (22) mọ́lé látàrí àdo olóró tí ó bú gbàmù ní Istanbul. Ènìyàn mẹ́fà (6) pàdánù ẹ̀mí wọn nígbà tí àwọn mọ́kànlélọ́gọ́rin (81) mínràn fi ara…