Rihanna Fi Fán-án-rán Fídíò Ọmọbíbí Inú Rẹ̀ Léde
Olùgba àmìẹ̀yẹ Rihanna ti fi fán-án-rán àwòrán rẹ̀ kan léde àti ti ọmọdékùnrin rẹ̀, lẹ́yìn tí ọmọ náà pé osù méje.
Àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ bá a dáwọ̀ọ́ ìdùnnú nígbà tí wọ́n rí fídíò rẹ̀ pẹ̀lú ọmọbíbí…