Iná Mọ̀nà -mọ́ná Àti Epo Gbówó Lórí Ní Orílẹ̀ Èdè Senegal
Ìjọba orílẹ̀ èdè Senegal ti kéde àlékún owó epo bẹntiróòlù àti iná mọ̀nà-mọ́ná ní orílẹ̀ èdè náà.
Àrẹ Macky Sall sọ ọ̀rọ̀ náà nínú ọ̀rọ̀ ìfiléde rẹ̀ ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kejìlá ọdún tí ó…