Orílẹ̀ Èdè Amẹ́ríkà Pèpè Fún Ìbágbépọ̀ Àlàáfíà Kí Ìgbé Ayé Le è Rọrùn Ní…
Asojú Orílẹ̀ Èdè Amẹ́ríkà sí Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà, Mary Beth Leonard ti pàrọwà sí ọmọ orílẹ̀ Nàìjíríà láti jẹ́kí àlàáfíà jọba lásìkò ìdìbò àti nígbà tí ìdìbò bá lọtán fún ìṣèjọba rere àti…