Take a fresh look at your lifestyle.

2023: Èmi Kò Tíì Yọwọ́ Kúrò Nínú Ìdíje Sípò Ààrẹ – Tinúbú

Olùdíje fún ipò ààrẹ lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Asíwájú Bọ́lá Ahmed Tinúbú pariwo síta tantan pé òun kò tíì yọwọ́ Kúrò nínú ìdíje sípò ààrẹ. Tinúbú, ẹni tó fi fídíò kan síta níbi to ti ń wa kẹ̀kẹ́ eré ìdárayá rẹ̀ nírọ̀lẹ́ ọjọ́ Àìkú láti…

Oríire Gómìnà Umahi: Ẹgbẹ Òṣèlú Ìpínlẹ̀ Ebonyi  Gbósùbà Fún Ilé Ẹjọ́

Ní ọjọ ọjó ẹtì, Alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC ti Ìpínlè Ebonyi, Stanley Emegha gbé òsùbà ràbàndẹ̀ fún ìdájọ tí ilé ẹjọ tó kalẹ̀ sí ìlú Abuja fún ìdájọ́ rere ìbò kòmẹsẹ̀ ó yọ ti ẹgbẹ́ òṣèlú APC tó gbé Gómìnà David Umahi wọlé bí Olùdíje òtítọ́ ti…

Kabul: Aa! Ìkọlù Ìpànìyàn Àti Igbẹ̀mi Ara Ẹni Ní Gbọ̀ngàn Ìdánwò Dá Ọ̀kàndínlógún Ẹ̀mí Ènìyàn…

Ìkọlù Ìpànìyàn àti ìgbẹ̀mí ara ẹni ní gbọ̀ngàn ìdánwò ti dá ọ̀kàndínlógún èmi ènìyàn légbodò tí ọ̀kè àìmọye ènìyàn sì farapa ní Kabul Olú ìlú Afghanístàn. Agbẹnusọ Ọlọ́pàá Kabul, Khalid Zadran sọ wípé ìṣẹ̀lẹ̀ náà sẹlẹ̀ ní gbọ̀ngàn ilé…

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nàìjíríà Gbé Ìgbésẹ Láti Dín Agbára Bánkìì Àpapọ, CBN  Kù

Àbádòfin kan láti dín agbára Báńkìì orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kù ti rékọjá ipele kíkà Kejì ní ilé Igbimo Asofin ní ọjó Ìṣẹ́gun. Ìwé àṣẹ náà ń wa ọ̀nà láti yan ẹlòmíràn yàtọ̀ sí Gómìnà CBN, gégébí Alága ti Ìgbìmọ̀ náà àti kí o yokúrò  ojúṣe…
button