Orílẹ̀-Ẹ̀dè Mozambique Rí Ààrùn Ọ̀bọ (Monkeypox) Àkọ́kọ́
Orílẹ̀-èdè Mozambique ti ri Ààrùn Ọ̀bọ àkọ́kọ́ he lati ìgbà tí àjọ World Health Organization, WHO, ti polongo rẹ̀ faye gbọ́ lati osù kárùn ún.
Ọkùnrin kan ni won ti se àyẹ̀wò rẹ ní Olu ilu ni Maputo pé o ti lùgbàdì àìsàn náà. Awọn…