Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọ́ Àwọn Tó Nílò Ìrànlọ́wọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Kí Wọ́n Tó Jáde Níbi Ìpàgọ́

Ọgọ́rùn ún ènìyàn káàkiri orílẹ̀-èdè yìí ni wọn ti gba ẹ̀bùn irinṣẹ́ ìrónilágbára lọ́wọ́ ìjọba orílè-èdè Nàìjíríà. Komisọ́na Ìjọba àpapọ tí orílè-èdè yìí fún àwọn àtìpó àti ogun léndé, Imaan Suleiman-Ibrahim ló pín àwọn ẹ̀bùn…
button