Take a fresh look at your lifestyle.

Òṣìṣẹ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Se Àjọyọ̀ Àyájọ́ Ọjọ́ Àwọn Òṣìṣẹ́

Àwọn òṣìṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà darapọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn káàkiri àgbáyé láti se àjọyọ̀ àyájọ́ ọjọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ti ọdún yí-Ọjọ́ Kínní Oṣù Karùn ún. Ní ìlú Àbújá, olú ìlú orílẹ̀-èdè yìí, àwọn òṣìṣẹ́ àti àwọn èèkàn péjọ sí…

Ìjọba Nàìjíríà Kó Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Yìí Kúrò Ní Orílè-èdè Sudan

Ìjọba orílẹ̀-èdè yí ti sọ pé kí àwọ ọmọ Nàìjíríà lọ fara balẹ̀ nítorí ọ̀pọ̀ ọkọ̀ böọ̀sì bọ̀gìnnì ní àwọn ti pèsè tó sì ńkó àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yí láti Sudan lọ sí Egypt. Akọ̀wé àgbà àjọ tó ń rí sí ìdẹ̀rùn àwọn ará…

Davido Gbóríyìn Fún Pípéjú-pésẹ̀ Àwọn Olólùfẹ́ Rẹ̀ Látàrí Eré Afúnilókun Aláìfàsìkò Ṣòfò Rẹ̀

Gbajúgbajà akọrin tàka-sùfé, David Adélékè, tí ìnangi rẹ̀ nì ń jẹ́ Davido ti gbóríyìn fún pípéjú-pésẹ̀ àwọn Olólùfẹ́ rẹ̀ látàrí eré afúnilókun aláìfàsìkò sòfò rẹ̀ tó se ní ìlú Èkó ní ọjọ́ Àìkú. Ó lọ sí ojú òpó ayélujára…
button