Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Bẹ̀rẹ̀ Ìmúgbóòrò Ibùdó Pápákọ̀ Ojú Òfúrufú

Ibùdó Pápákọ̀ Ojú Òfúrufú ti Shehu Musa Yar’adua, ìpínlẹ̀ Katsina, Àríwá ìwọ̀ Oòrùn Nàìjíríà ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ ìmúgbóòrò rẹ̀ láti jẹ́ kí ọrọ̀ ajé àti ètò ààbò rú gọ́gọ́ si. Mínísítà fún ètò ìrìnà ọkọ̀ Òfúrufú, sọ eléyìí di mímọ̀ níbi…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Yàn Ènìyàn Méjìlélógún Tí Yòó Ṣe Etò Kòkárí Ìgbéjọba Kalẹ̀

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó ti yàn àwọn Ènìyàn Méjìlélógún ti yòó sè etò ayẹyẹ ìbúra fún Gómìnà Babajide Sanwo-Oluati igbákejì rẹ̀ Dókítà Kadri Hamzat. Kọmísọ́nà fún ètò ìròyìn àti ọgbọ́n àtinúdá, Ọ̀gbẹ́ni Gbenga Ọmọ́tọ̀sọ́ sọ pé àwọn…

Ìjọba Nàìjíríà Kó Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Yìí Kúrò Ní Orílẹ̀-èdè Sudan

Ìjọba Nàìjíríà ti kó ọ̀pọ̀ omọ Orílẹ̀-èdè yìí kúrò ní Orílẹ̀-èdè Sudan láti Egypt. Kíkó àwọn ènìyàn náà pátápátá kúrò ní Orílẹ̀-èdè Egypt yóò wáyé ó pẹ́ tán ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ karùn ún osu karùn ún. Ọkọ̀ òfúrufú ti…

Ọjọ́ Àwọn Òṣìṣẹ́: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Anambra Yóò Tẹ̀síwájú Láti Jẹ́ Kí Ayé Dẹrùn Fún Àwọn Òṣìṣẹ́

Ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra ní Gúsù - ìlà oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sọ pé ojúṣe àwọn ni láti jẹ́ kí ayé túbọ̀ dẹrùn fún àwọn òṣìṣẹ́ . Olórí àwọn òṣìṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ náà, Theodora Igwegbe sọ èyí ní ibi ìpolongo ìhìnrere rẹ̀ fún àwọn…
button