Ikọ̀ Ọmọ Ogun Sọ Agbára Àwọn Agbésùòmí Di Òtu Bántẹ́ Ní Ọ̀nà Kàdúná Sí Záríà
Ikọ̀ ọmọ ogun àpapọ orílẹ̀ èdè yìí ti sọ agbára àwọn agbésùmọ̀mí méjì ní ọ̀nà Kàdúná sí Záríà ní ìjọba ìbílẹ̀ Igabi ti ìpínlẹ̀ Kàdúná di òtu bántẹ́.
Eléyìí jẹyọ nínú atejade ti wọ́n…