Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹni Tó Ní Ilégbèé Kan Ní Orílẹ̀ Èdè Kenya Tó Dáwọ Lulẹ̀ Yóò Kojú Ẹ̀sùn

Àwọn alákóso Ọlọ́pàá ní Orílè-èdè Kenya ti sọ pé ẹni tó ní ilé alájà máàrún tó dàwó lulẹ̀ ní ọ̀ṣẹ̀ tó kọjá ní agbègbè Nairobi yóò kojú ẹ̀sùn Ìpànìyàn Ilé náà lulẹ̀ sórí ilé tó sún mọ́ọ tó sì pa ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn. Olópàá sọ pé wọ́n…

Àwọn Gómìnà Nínú Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC SE Ìpàdé Pọ̀ Pẹ̀lú Àjọ Òṣìṣẹ́ Ti Ẹgbẹ́ Oṣèlú APC

Gómìnà méfà, láti inú ẹgbẹ́ òṣèlú APC ati awọn ọmọ ẹgbẹ́ olupolongo ìbò aarẹ nínú ẹgbẹ́ kan naa ti wa ninu Ipade pẹlu Àjọ Òṣìṣẹ́ Ti ẹgbẹ́ APC . Ipade náà n waye ni gbọ̀ngàn ìpàdé ti ẹgbẹ òṣèlú APC ní Abuja. . Alága gbogbo gbò fún…

Ajíbádé Yóò Ṣáájú Ikọ̀ Falcons Nígbàtí Wọ́n Bá Dojúkọ Nadeshiko Ní Ìlú Kobe

Ògbóntarìgì agbábọ́ọ̀lù Ajíbádé yóò ṣáájú Ikọ̀ tí àwọn Obìnrin orílẹ̀-èdè yìí nígbà tí wón bá fesẹ̀wonsẹ̀ pẹ̀lú ojúgbà wọn láti orílè-èdè Japan ní ọjó Ọjọ́rú ní Ìlú Kobe. Ara ẹlẹṣẹ̀ ayò, Onome Ebi ṣẹṣẹ n bọ̀ sipò látàrí ifarapa tó ní…

Ààrẹ Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Àwọn Ológun Fún Ìdásílẹ̀ Àwọn Tí Wọ́n Kó Nígbèkùn

Ìgbìmọ̀ eléni méje tí ààrẹ ti olórí ikọ̀ ti aabo elétò awọn ọmọ ogun látọwọ́ CDS Ogágun Lucky Irabor ti ríi dájú pé wọ́n dá ènìyàn mẹ́tàlélógún tókù sílẹ̀ nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ìkóni ní gbèkùn ti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Boko Haram ní ọ̀nà Abùjá ṣí…
button