Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Òsèlú NNPP Sẹ́ Àhesọ Ọ̀rọ̀ Pé Wọ́n Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Òsèlú People’s Democratic Party 

  Ẹgbẹ́ Òsèlú New Nigeria People’s Party (NNPP) ti sẹ́ àhesọ ọ̀rọ̀ pé wọ́n ti lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òsèlú People’s Democratic Party látàrí ìbò ọdún tó ń bọ̀. Ẹgbẹ́ rọ àwọn ènìyàn láti má tẹ́tisílẹ̀ sí kùbákùngbé ọ̀rọ̀ náà wípé kosi…

Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà Rí Ọgọ́fà Bílíọ̀nù Dọ́là Gbà Padà Nínú Ìgbésẹ̀ Láti Fòpin Sí Ìwà Òbàyéjé .

Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà Rí Ọgọ́fà Bílíọ̀nù Dọ́là Gbà Padà Nínú Ìgbésẹ̀ Láti Fòpin Sí Ìwà Òbàyéjé . Mínísítà fún ètò ìròyìn àti ọ̀rọ̀ àṣà, Ọ̀gbẹ́ni Láí Mohammed ti sọ pé ìjọba yìí tí ri Ọgọ́fà bílíọ̀nù dọ́là àti owo ilẹ̀ òkèèrè gba padà láti…
button