Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ifowopamọ, Àwọn Onísòwò Tó Bá Kọ́ Owó Àtíjọ́ Yóò Jẹ̀ Iyán Rẹ̀ Níṣú – Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano tí ṣé ìkìlọ pé òún kó ní lọrá látí fá ìgi lé àwọn ìwé-àṣẹ tí àwọn oníṣòwò pàtàkì tàbí gbé ìgbésẹ lórí ẹnikẹni tó kọ̀ látí gbà àwọn òwò náírà àtijọ. Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje tó fí ìkìlọ náà lélẹ̀ nínú àtẹ̀jáde…

Ààrẹ Buhari Kí Dókítà Pate Kú Oríìré Fún Yíyàán Sí Ipò Gẹ́gẹ́ Bí Olùdarí Àgbà Gavi

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí kí Olùdarí Àgbà àtí Aláṣẹ tí Gavi Vaccine Alliance, Dókítà Muhammad Ali Pate. Ó sọ pé òún ní ìrètí látí ṣiṣẹ́ ní pẹkipẹki pẹ̀lú rẹ̀ látí mú ètò ìlera orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lágbára sí àtí àwọn ọrọ̀ ìlera àgbáyé…

Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Ṣé Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Ọ́lọ́tẹ̀ Nínú Rògbòdìyàn Tó Ṣẹ̀lẹ̀ Ní Tigray

Ààrẹ Eritrea Isaias Afwerki tí fí ẹsùn kán Orílẹ̀-èdè America fún àtìlẹ́yìn tí wọ́n ṣé fún àwọn ọ́lọ́tẹ̀ tí Tigray làkókò ogún àbẹ̀lé tó parí láìpẹ́ yíì ní àríwá Ethiopia. Ààrẹ Afwerki ń sọrọ làkókò ifọrọwanilẹnuwo pẹ̀lú àwọn òníròyìn…

Ìṣẹlẹ Ìjì-ilẹ̀ Turkey-Syria: Ipò Àìrí Ilé Gbé Àwọn Olùgbé Àgbègbè Náà

Ipò tí àwọn ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn tó dì aláìní ilé lórí nípasẹ̀ ìwárírì-ilẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ ní Turkey àtí Syria ń pọ̀si títí dì Ọjọ́bọ̀, nígbà tí ìrètí pìn lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn pé bóyá wọ́n ṣì wà láàyè láàrín àwọn ilé tó wò lulẹ̀. Ìṣẹlẹ yìí tó…

Mínísítà Ètò Ẹ̀kọ́ Pàṣẹ Kí Wọ́n Tí Àwọn Ilé-ẹ̀kọ́ Gíga Fún Ìdìbò Gbogbogbò 2023

Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mallam Adamu Adamu, tí pàṣẹ kí wọ́n tí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga Káàkiri orílẹ̀-èdè yìí fún ìdìbò Ààrẹ àtí Gómìnà lọdún yìí. Ìgbákejì Akọ̀wé Alàkóso Ọ̀gbẹ́ni Christopher Maiyaki tí National…
button