Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Rọ Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Láti Gbá Àlàáfíà Láàyè Níbí Ètò Ìdìbò Gbogbogbò…
Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ahmad Lawan tí rọ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ṣé jẹ́jẹ́ níbi ìdìbò gbogbogbò tó ń bọ̀.
Sẹnetọ̀ Lawan tún rọ wọ́n látí wà sí àgọ́ ìdìbò wọ́n ní àwọn ọjọ́ tí á yà sọtọ fún Ìbò kí…