Take a fresh look at your lifestyle.

INEC kéde Hyacinth Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Gẹ́gẹ́ Bí Olúborí Ìdìbò Gómìnà Benue

Àjọ élétó ìdìbò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, INEC, tí kéde Rev. Fr. Hyacinth Alia tí ẹgbẹ́ òṣèlú (All Progressive Congress) APC, gẹ́gẹ́ bí ẹní tó jáwé olúbóri nínú ìdìbò Gómìnà àtí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Benue, Àárín…

Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè Kí Àwọn Aṣojú Angola, Britain Àtí America Kú Ìṣẹ́ Takuntakun

Mínísítà fún Ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèèrè tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Geoffrey Onyeama tí ṣé ètò ìdágbéré sí aṣojú Angolan tí yóò fí ipò sílẹ̀, Eustaquio Quibato, Kọmisọna gíga tí Ìlú Gẹ̀ẹ́sì (British High Commissioner) Catriona Laing àtí aṣojú America,…

Olórí Ọmọ-Ògún Ojú-Omí Ṣé Ìpàdé Àwọn Òṣìṣẹ́ Ojú-Omí Ilẹ̀ Áfíríkà

Olórí Òṣìṣẹ́ Ọ̀gágun Nàìjíríà, Ìgbákejì Admiral Awwal Zubairu Gambo yóò lọ́ sí Ìpàdé àwọn ọmọ-ogún ojú-omí (African Maritime Forces Submit) ní Cape Verde. O dárí àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́ sí àpéjọ ọlọjọ mẹ́ta ti yóò bẹ̀rẹ̀ ní…

Ẹgbẹ́ Oníròyìn Nàìjíríà Pẹ̀lú Àwọn Àkẹgbẹ́ Wọ́n Látí Orílẹ̀-èdè America Ṣé Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Àwọn…

Ẹgbẹ́ àwọn òníròyìn Nàìjíríà (NUJ), Ìgbìmọ̀ Ìpínlẹ̀ Èkó lábẹ́ Alága wọ́n Ọ̀gbẹ́ni Adeleye Ajayi, tí ṣé ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan ní àgbègbè ikẹkọ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́. Gẹ́gẹ́ bí èròngbà ẹgbẹ́ náà láti rí dájú pé àwọn òníròyìn ìpínlẹ̀ Èkó ìmọ…

Ètò Ìdìbò Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Osun Kéde Ìsìnmi Lẹ́nù-iṣẹ́ Ọjọ́ Ẹtì

Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke tí kéde ìsinmi lọjọ́ Ẹtì ṣáájú ètò ìdìbò ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ náà tí yóò wáyé ní ọjọ́ Ẹtì. Èyí wà nínú àtẹ̀jáde tí agbẹnusọ Gómìnà, Mallam Olawale Rasheed sọ́ fún òníròyìn VON ní Osogbo…

Ààrẹ Buhari Kóró-ojú Sí Ìkọlù Túntún Tí Àwọn Ẹ́ṣìn-ó-kọ́ku Ṣé Ní Ìpínlẹ̀ Kaduna

Ààrẹ Muhammadu Buhari sọ́ wípé iyalẹnu ló jẹ́ fún òún látí gbọ́ pé àwọn ẹsìn-ó-kọ́ku tún ṣé ikọlù ìpànìyàn sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀mí aláìṣẹ ní ìjọba ìbílẹ̀ Zangon Kataf ní ìpínlẹ̀ Kaduna. Ààrẹ Buhari sọ pé kí àwọn òṣìṣẹ́ Ilé-iṣẹ́ Ààbò…
button