Ẹgbẹ́ Àwọn Ọdọ Olùwẹ̀ Ọmọ Nàìjíríà Dé Sí Egypt Fún Ìdíje
Ẹgbẹ́ ọdọ Nàìjíríà tí dé sí Orílẹ̀-èdè Egypt fún ìdíje ọdọ ilẹ̀ Áfíríkà ní Egypt tí a ṣètò fún ọjọ́ kọkandinlọgbọn oṣù kẹ́rin sí ọjọ́ kẹ́ta oṣù karùn-ún ọdún 2025.
Ẹgbẹ́ náà tó ní àwọn olùwẹ̀ mẹ́rinlá (14), àwọn ọmọkùnrin mẹjọ (8)…