Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Élétó Ìdìbò INEC Ṣètò Àwọn Ìgbìmọ̀ Látí Ṣé Àtúnyẹwò Àwọn Ìdìbò Gbogbogbò Tó Kọjá

Àjọ élétó ìdìbò tí Orílẹ̀-èdè yìí INEC tí ṣètò àwọn ìgbìmọ̀ inú-ilé méjì látí ṣé àtúnyẹwò àtí ṣé àkọsílẹ̀ àwọn iṣẹ́ tí Ìdìbò Gbogbogbò 2023. Alága Àjọ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu ṣé ìfilọ́lẹ̀ àwọn ìgbìmọ̀ náà ní Ọjọ́rú ní Abuja,…

Ipò Àgbẹ́núsọ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú-Ṣófin Kẹ́wàá, Àárín Gbùngbùn Àríwá Ló Tọ́ Sí – Gagdi

Aṣojú Yusuf Gagdi (APC Plateau) sọ pé Àárín gbùngbùn Àríwá (North Central) yẹ̀ látí gbà ẹsan ìgbìyànjú rẹ̀ nínú ètò ìdìbò tó kọjá pẹ̀lú ipò agbẹnusọ ilé ìgbìmọ̀ asojú-ṣófin Orílẹ̀-èdè yìí. Gagdi sọ èyí nígbà tó n bá àwọn oníròyìn sọrọ…

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Ghana Ní Alága Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn Ìwé Lórí Ààrẹ Nàìjíríà

Ààrẹ Nana Akufo-Addo tí Orílẹ̀-èdè Ghana ní á n'ìrètí látí ṣé Alága ìgbéjáde àtí ìfilọ́lẹ̀ àwọn ìwé túntún méjì kàn lórí àwọn ipá tí Aare Muhammadu Buhari kó lórí ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè ní ọjọ́ Ẹtì, ọjọ kokandinlogun 19 Oṣù Kàrún ùn, ní…

Ààrẹ Nàìjíríà Ṣàfihàn Ìbànújẹ́ Rẹ̀ Lórí Ìkọlù Apànìláyá Tó Ṣẹ̀lẹ̀ Láìpẹ́ Yíì

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí kẹ́dùn lórí ìpàdánù ẹ̀mí méjì tí àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ ilẹ̀ America àti ọlọ́pàá Nàìjíríà méjì tí wọ́n tẹ̀lé wọ́n níbí ikọlù tí àwọn agbebọn kàn ṣé ní ìjọba ìbílẹ̀ Ogbaru ní Ìpínlẹ̀ Anambra. “Inú mi bà jẹ́ gan-an…

Àjọ Àgbáyé (UN) Ń Béèrè Fún Bílíọ̀nù Mẹ́ta-Dín-Díẹ Dọla ($2.6B) Fún Iṣẹ́ Ọmọnìyàn Ni Sudan

Ìgbìmọ̀ élétó Ọmọnìyàn ti Àjọ Àgbáyé (UN) tí ń bẹ̀bẹ̀ fún Bílíọ̀nù Mẹ́ta-Dín-Díẹ Dọla ($2.56B) látí ṣé ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn tí àáwọ̀ tó ṣẹ̀lẹ̀ láàrín àwọn ọmọ Ogún Sudan àtí àwọn ẹgbẹ́ àlátákò ní Orílẹ̀-èdè Sudan ṣé àkóbá fún. Òṣìṣẹ́…

Ìpàdé Ìgbìmọ̀ Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ń Lọ́ Lọ́wọ́

Ààrẹ Muhammadu Buhari ní ó ń dárí ìpàdé tí Ìgbìmọ̀ Àwọn Aláṣẹ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó ń lọ́ lọ́wọ́ ní ilé ìpàdé Ìgbìmọ̀ tí Presidential Villa, Abuja. Ìgbákejì Ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo, Olórí Òṣìṣẹ́ sí Ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ibrahim…

Olùkọ́ní Flying Eagles Ní Ìgbàgbọ́ Lórí Ìkọ Rẹ̀ Lẹyìn Àbájáde Ifẹsẹwọnsẹ Pẹ̀lú Ìkọ Colombia

Ìkọ Flying Eagles tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà já àjákú akátá pẹ̀lú ìkọ Colombia ní àmì ayò mẹ́ta-mẹ́ta 3-3 ní ọjọ́ Ìṣẹgun (Tuesday) ní igbaradi sí ìfé Àgbáyé FIFA U-20 World Cup, tí yóò bẹ̀rẹ̀ ní Ogúnjọ́ Oṣù Kàrún ùn, ní Tristán Suárez, Buenos…

Orílẹ̀-èdè America Ṣé Ìlérí Ìbáṣepọ̀ Rẹ̀ Pẹ̀lú Ìjọ̀ba Túntún Tí Ń Wọlé Bọ̀ Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Àkọwé ìjọ̀ba America kékeré Anthony Blinken tí fí dá Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà túntún, Bola Ahmed Tinubu lójú pé Orílẹ̀-èdè America yóò só ìbáṣepọ̀ wọ́n pẹ̀lú tí Nàìjíríà doin-doin lásìkò ìṣàkóso ìjọba túntún náà. Blinken, nínú àlàyé rẹ̀…

Àjọ WHO Kìlọ fún Àwọn Ilé-iṣẹ́ Ìlera Lórí Lílò “AI” Fún Ìtọjú Àtí Ìwádìí Ìlera Ọmọnìyàn

Àjọ Ìlera Àgbáyé (World Health Organisation WHO) tí ṣé ìkìlọ fún àwọn ilé-iṣẹ́ àtí òṣìṣẹ́ ìlera ní ọjọ́ Ìṣẹgun (Tuesday) lórí lílò ìṣẹ́ oyè atọwọda (Artificial Intelligence AI) fún ètò ìlera ọmọnìyàn nítori wípé àwon data tí AI ń ló látí…
button