Hajj 2023: Kaduna Pàdánù Obìnrin Tó Ń Gbìmọ Látí Lọ́ Sílé Olúwa
Àjọ àrìnrìn-àjò lọ́ sí Mecca tí Ìpínlẹ̀ Kaduna tí kéde ikú ọkàn lára àwọn àrìnrìn-àjò. Amina Damari pẹ̀lú nọ́mbà ìforúkọsílẹ̀ KD363 láti ìjọba ìbílẹ̀ Sabon Gari ní ìpínlẹ̀ Kaduna.
Èyí ní amugba lẹgbẹ pàtàkì sí Akọ̀wé Aláṣẹ tí Àjọ náà,…