Osimhen Fẹ́ Gbábọ̀ọ́lù Fún Manchester United Tàbí Real Madrid – Bagni
Àgbábọ́ọ̀lù Ọmọ Nàìjíríà, Victor Osimhen fẹràn láti gbábọ̀ọ́lù fún bóyá Manchester United tàbí Real Madrid ṣáájú àwọn ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù mìíràn tí n wàá látí ṣojú wọ́n.
Àgbábọ́ọ̀lù Napoli tẹlẹ rí, Salvatore Bagni tó gbá ìfé Scudetto àti…