Take a fresh look at your lifestyle.

Gusau Bẹ́ Àwọn Olùkọ́ní FIFA Látí Ṣé Ìrànlọ́wọ́ Fún Ìdàgbàsókè Àwọn Àfọn-fèèrè Nàìjíríà

Ààrẹ tí Àjọ Àwọn Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà (Nigeria Football Federation NFF) Alhaji Ibrahim Gusau ní Ọjọ́bọ̀ pé àwọn olùkọní FIFA ti wọ́n wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún àwọn ètò mẹ́ta kàn, látí ṣé ìrànlọ́wọ́ látí mú ìlọsíwájú bá àwọn Olùdarí èrè…

Cleverly Kìlọ Fún Àwọn Aráàlú Látí Yàgò Fún Ìkọlù Olúilé-iṣẹ́ India Ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì

Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè tí Orílẹ̀-èdè Gẹẹsi James Cleverly kìlọ pé ìjọba Orílẹ̀-èdè náà lòdì sí èyíkéyìí ikọlù sí Ilé-iṣẹ́ ìjọba gíga India ní Ìlú London. Èyí wá lẹyìn ìròyìn ìwé pélébé kàn tó jáde nípa ìwọ́de fún àtìlẹ́yìn Ìpínlẹ̀ ọtọ…

Ọwọ́ Òfin Tẹ̀ Òṣìṣẹ́ Ilé-iṣẹ́ Oúnjẹ Kàn Ní Kenya Látàrí Ìtẹ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn Lójú Mọlé

Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá tí bá àwọn òṣìṣẹ́ ilé oúnjẹ Kenya mẹ́ta kàn lẹyìn ẹsùn ifipa bọ́ṣọ́ lọrùn àwọn òṣìṣẹ́ bìrin wọ́n láti ṣàyẹ̀wò ẹní tí ó ùn ṣé nkán oṣù rẹ̀ lọ́wọ́, ìròyìn abẹ́lé sọ. Nínú àlàyé kàn lórí ojú òpó ayélujára Ilé-iṣẹ́ Oúnjẹ…

Anti-Gay Bill: Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ghana Tí Ń Jà Fítáfítá Láti Dènà Òfin Ìbálòpọ̀ Ọkùnrin Àtí Ọkùnrin

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ní Orílẹ̀-èdè Ghana tí ṣé àtìlẹ́yìn àtúnṣe sí ìwé-àṣẹ làti wọ́n ìjìyà ẹwọn ọdún mẹ́ta fún ẹnikẹ́ni tó bá tún polongo pẹ̀lú ìdánimọ̀ Ìbálòpọ̀ Ọkùnrin àti Ọkùnrin, Obínrin àtí Obínrin bíi LGBT. Àwọn ènìyàn tó bà tún ṣé…

Ààrẹ Tinubu Kọ̀ Ìwé Sí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣòfin Lórí Àwọn Olórí Ologún Túntún

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí kọ̀wé sí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣòfìn látí ṣé àkíyèsí àwọn olórí ológun títún ní orílẹ̀-èdè yìí. Agbẹnusọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣojú ṣòfin Honourable Tajudeen Abbas ló ká ìwé náà ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin.…
button