Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Àjọ Kàn Gbá Mílíọ̀nù Owó Dọla Pẹ̀lú Àwọn Ìbọn Ní Pápá-kọ̀ Òfurufú Zambia

Àjọ tó ń rí sí ajẹ́bánú owó ìlú àtí oògùn olóró tí Orílẹ̀-èdè Zambia gbà ìyè tó súnmọ́ mílíọ̀nù Mẹ́fà dọla $6m (£ 4.7m) ní pápá-kọ̀ Òfurufú ní Olú-ìlú, Lusaka. Bákannáà ní wọ́n gbá ìbọn márùn, magasini méje, àwọn ọtá ìbọn ọgọ́fà àtí…

Ìpínlẹ̀ Gombe Ní Látí Ṣé Àjọṣépọ̀ Pẹ̀lú Ìgbìmọ̀ Aláàbò Ọlọ́pàá Àgbègbè Náà

Ìgbákejì Gómìnà tí Ìpínlẹ̀ Gombe, Manassah Jatau tí tún sọ́ èròngbà ìjọba Ìpínlẹ̀ náà látí jẹ́ alabaṣepọ pẹ̀lú Ìgbìmọ̀ Ààbò àwọn Ọlọ́pàá àgbègbè náà àtí èyíkéyìí Àjọ tó pinnu látí ríi dájú pé ètò ààbò wà fún àwọn ènìyàn atí oun-ìní wọ́n ní…

Àbójútó Ààbò: Ìpínlẹ̀ Niger Ń Fẹ́ Àlékún Àtìlẹ́yìn Àwọn Ológun

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Niger, Mohammed Bago tí ráwọ́ ẹ̀bẹ̀ àtìlẹ́yìn àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà sí látí kojú àwọn ìpenija ààbò ní Ìpínlẹ̀ náà. Gómìnà Bago sọ èyí lásìkò àbẹwò rẹ̀ sí si Ọ̀gá àgbà ilé-iṣẹ́ ológun lorilẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọgagun…

Orílẹ̀-èdè Niger: ECOWAS Yóò Ṣé Ìjíròrò, Ló Ọ̀gbọ́n Àtínudá Látí Dá Ìjọba Tiwa-n-tiwa Pàdà Sí Àkóso…

Alága tí ECOWAS àti Ààrẹ Nàìjíríà Bola Tinubu, sọ pé ẹgbẹ́ náà yóò tẹ̀síwájú látí ló ọ̀gbọ́n ètò òṣèlú Tiwa-n-tiwa àtí ṣé Ìjíròrò pẹ̀lú gbogbo àwọn alẹnu-lọrọ, látí mú ìjọba tiwantiwa pàdà sípò ní Orílẹ̀-èdè Niger. Alága àtí Aláṣẹ…

Ìfipágbàjọba Ní Niger: Alága ECOWAS Gbèrò Ojútùú Láíláí Sí Ọrọ̀ Òṣèlú Orílẹ̀-èdè Náà

Alága ECOWAS àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Tinubu sọ pé Ojútùú kàn gbọ́dọ̀ wà fún ìdààmú òṣèlú orílẹ̀-èdè Niger látí wà ní àlàáfíà láíláí ní àpá Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà àtí gbogbo ilẹ̀ Áfríkà. Nitorinà o tí késí àwọn ẹlẹgbẹ rẹ̀ láti ṣé…
button