Àjọ Ọlọ́pàá, Ẹgbẹ́ Akọ̀ròyìn Yóò Ṣé Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Látí Gbógun Tí Ìwà-ipá Ni Ìpínlẹ̀ Ebonyi
Àwọn òníròyìn ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi, lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ Akọ̀ròyìn ní Nàìjíríà NUJ, tí ṣé àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá látí kojú àwọn ìwà ọdaràn àti Ìwà-ipá Ni Ìpínlẹ̀ náà.
Àdélé Alága ẹgbẹ́ náà, Ọ̀gbẹ́ni Uchenna Inya sọ wípé àwon ọmọ ẹgbẹ́…