Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Yóò Sọ̀rọ̀ Níbí Àpéjọ Àjọ Àgbáyé Ẹlẹ̀ẹ́kejìdínlọgọ́rin

Ààrẹ Nàìjíríà Bola Tinubu yóò sọ̀rọ̀ níbí àpéjọ Àjọ Àgbáyé ẹlẹ̀ẹ́kejìdínlọgọ́rin ní ilé-iṣẹ́ àjọ náà ní New York ní ọjọ́ Ìṣẹgun, ọjọ́ kokandinlogun, Oṣù Kẹsán, Ọdún 2023. Àjọ Àgbáyé tí ṣàlàyé pé Ààrẹ Nàìjíríà yóò bá gbogbo àgbáyé…

Gómìnà Borno Tẹ́lẹ̀ Gbóríyìn Fún àwọn ànímọ́ aṣáájú-ọ̀nà ti VP Shettima

Gómìnà tẹ́lẹ̀ tí Ìpínlẹ̀ Borno, Ali Modu-Sheriff tí yìn Ìgbákejì Ààrẹ Nàìjíríà, Kashim Shettima látàrí ìwà ìgbìyànjú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olórí. Modu-sheriff sọ̀rọ̀ yíì lásìkò tó n bá àwọn òníròyìn sọ̀rọ̀ ní ilé ìjọba àpapọ̀ ní kété tó ṣé…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣọ̀fọ Olùṣètò Àsìá Orílẹ̀-èdè Náà

Ìjọba Àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ń ṣọ̀fọ̀ ikú olùṣe àsíá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Pa Taiwo Akinkunmi tó kú ní ẹni ọdún mẹ́rìnlélọ́gọ́rin , ní ilé rẹ̀ ní Ìbàdàn, lẹ́yìn àìsàn ránpẹ́. "Inú mí bàjẹ́ látí gbọ́ ìròyìn tí ikú Pa Taiwo…

Ìdìtẹ̀gbájọba Gabon: Wọ́n Yán Gen. Brice Nguema Gẹ́gẹ́bí Alákóso Túntún

Àwọn òṣìṣẹ́ ológun tó gbìmọ̀ gbájọba ní Gabon ní kùtùkùtù òwúrò Ọjọ́rú tí dárúkọ General Brice Oligui Nguema gẹ́gẹ́ bí Olùdarí túntún ní Orílẹ̀-èdè náà, wọ́n sì mú ọkàn nínú àwọn ọmọ Ọ̀gbẹ́ni Bongo fún iṣọtẹ. Ààrẹ Ali Bongo tí wọ́n gbá…

Mínísítà Olú-ìlú Nàìjíríà Gbèrò Látí Máà Ló Owó Tí Ilé-iṣẹ́ Náà Pá Fún Àwọn Iṣẹ́ Àkànṣe

Mínísítà tí Olúìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Abuja, Nyesom Wike tí kéde pé láti àkókò yíì, àwọn owó tí wọ́n bá pá lábẹ́lé (IGR) ní wọ́n yóò máa ló fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe kàn. Mínísítà náà sọ làkókò tó ń ṣàlàyé àwọn ìgbésẹ̀ akin látí ṣé àtúnṣe…
button