Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Tako Ẹ̀sùn Ìdààmú Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Ní Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Ethiópíà

Ilé-iṣẹ́ Ìjọba tó ń rí sí ọ̀rọ̀ Òkèèrè lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fi àtẹ̀jáde kàn tako àwọn ẹ̀sùn tí Dókítà Paul Ezike kàn tó ṣé láìpẹ́ yìí nípa ipò àwọn ẹlẹ́wọ̀n Nàìjíríà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Kaliti, ní orílẹ̀-èdè Ethiópíà. Àlàyé náà, tí…

Ààrẹ Nàìjíríà Fí Ètò Ààbò Orílẹ̀-èdè Náà Ṣáájú Nínú Ìjọba Rẹ̀ Pẹ̀lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ìmọ-òye Lọ́nà Tó…

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí tún fí ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ìjọba òun tí ṣé Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ìmọ-òye láàrin àwọn ilé-iṣẹ́ Ààbò tí orílẹ̀-èdè yìí, láti mú ètò Ààbò ní okunkundun, kí àlàáfíà bá lé j'ọba fún àwọn ará ìlú. Ààrẹ…

Mílíọ̀nù Mẹ́ta Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Yóò Ní Ànfààní Láti Kópa Nínú Ètò Ẹ̀kọ́ Kàn

Ó jú mílíọ̀nù mẹ́ta àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò ní anfààní láti kópa nínú ètò ìmọ-ẹrọ pàtàkì kàn tí ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú WEMA Bank Plc. Ètò náà tí wọ́n pé ní 'Skillinovation' yóò pèsè àwọn anfààní…

Ẹgbẹ́ Àwọn Alàkóso Ilé-ìwé Gírámà Yóò Tẹ̀síwájú Láti Sé Àtìlẹ́yìn Iṣẹ́ Náà

Àkójọpọ̀ àwọn alákóso tí àwọn ilé-ìwé Gírámà ní Nàìjíríà, , sọ pé àwọn yóò tẹ̀síwájú láti ṣé àtìlẹ́yìn àwọn iṣẹ́ alamọdaju àti gbá àsìá ẹgbẹ́ náà duro. Èyí ní Ààrẹ ẹgbẹ́ ANCOPSS, Alhaji Bello Gupa sọ dì mímọ lákókó ìpàdé ìgbìmọ̀ náà tó…

Ìjọba Nàìjíríà Rọ́ Àwọn Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ Láti Bọ̀wọ̀ Fún Àṣẹ Ilé-ẹjọ́

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ké sí àwọn àjọ òṣìṣẹ́ láti má ṣe gúnlé yanṣẹlodi, kí wọ́n bọ̀wọ̀ fún àṣẹ tí Ilé Ẹjọ́ pá wọ́n ọjọ́ karún-ùn oṣù kẹfà. Ilé-ẹjọ́ tí pàṣẹ fún Ìgbìmọ̀ àwọn Òṣìṣẹ́ (NLC) àtí (TUC) láti má gúnlè iyanṣẹlodi latari…
button