Take a fresh look at your lifestyle.

Gaza: Nàìjíríà Bú Ẹnú Àtẹ́ Lu Ikọlù Sáwọn Oníròyìn, Wọ́n Sí Ń Pè Fún Ìdádúró Ogún

Mínísítà fún Ìròyìn tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Idris, tí dá àwọn Ológun Israeli lẹ́bi fún bí wọ́n ṣé ń tẹ́ ẹtọ́ ọmọnìyàn àwọn oníròyìn mọ́lẹ̀ nínú ogún tí nlọ́ lọ́wọ́ ní Palestine, pẹ̀lú bí wọ́n ṣé ń pá àwọn akọròyìn ní ipakupa.…

Ilé-ẹ̀kọ́ Gíga Áfríkà Yàn Ọmọ Nàìjíríà Gẹ́gẹ́bí Ìgbákejì Olórí Ilé-ẹ̀kọ́ Náà

Ọkàn nínú àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n Obìnrin tí ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lórí Èdè àtí Ìbáraẹnisọ̀rọ̀, Ọ̀jọ̀gbọ́n Bolanle Akeredolu-Ale, ní wọ́n tí yàn gẹ́gẹ́bí Ìgbákejì àdarí ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí 'Pan African University', tí Àjọ 'African Union…

Ilé-iṣẹ́ Ọmọ-ogún Nàìjíríà Fún Àwọn Ọmọ-ogún Márùn-ùn Ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa

Alákóso '4 Special Forces Command' tí àwọn ọmọ-ogún tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí fún àwọn òṣìṣẹ́ Ọmọ-ogún márùn fún iṣẹ́ ríbiríbi tí wọ́n ń ṣé ní ẹnú iṣẹ́ wọ́n. Alákóso, Major General Hillary Nzan sọ pé ẹbùn yí wà látí ṣé ìwúrí fún wọ́n…

Ìbẹ̀wò Ààrẹ Tinubu Sí Qatar Ní Látí Mú Ìbáṣepọ̀ Orílẹ̀-èdè Méjèèjì Gbòòrò Sí

Ààrẹ tí sọ pé àbẹwò tí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu sí Qatar ní èròngbà látí mú ifọkanbalẹ ètò ọrọ̀-àjé láàrín Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àtí ìjọba Qatar lágbára sí. Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Ààrẹ lórí ìròyìn àtí Ìlànà,…

Àwọn ikọlù Ìlú Rafah Ń Ṣé Idíwọ́ Fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìrànlọ́wọ́ Àjọ Àgbáyé

Ẹ̀ka Ìrànlọ́wọ́ àti Iṣẹ́ tí Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè fún Àwọn Olùwá-ibi-ìsádi Palestine ní Ìhà Ìlà Oòrùn tí Àjọ Àgbáyé (UNRWA), sọ pé àwọn ìkọlù òfurufú tí ó pọ̀ sí i ní Rafah ní “ìbẹ̀rù tí ó ga” fún “àwọn iṣẹ́ ìgbòkègbodò Ọmọnìyàn tí ó…

Ào Dá Iṣẹ́ Sílẹ̀ Lọ́pọ̀lọpọ̀ Lati Kojú Ìpèníjà Ẹ̀ka Ètò Ọrọ̀-àjé Wà – Ààrẹ Tinubu

Ààrẹ Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí ṣé àfihàn díẹ̀ nínú àwọn ètò ìṣàkóso rẹ̀ látí ṣ'èdá iṣẹ́ lọ́pọ̀lọpọ̀ láti mú kí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pá owó ilọpo méjì sí èyí tó wà tẹ́lẹ̀ kí 'Gross Domestic Product (GDP) tí orílẹ-èdè lè gòkè sí.…
button