Ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Orílẹ-èdè Nàìjíríà Ń Lọ Lọ́wọ́
Ìpàdé inú fọ́nrán tì Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ orílẹ-èdè yìí tó n lọ ni ilé Ìgbìmọ̀ Ààrẹ ní Abùjá, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari jẹ́ Alága ìpàdé náà.
Lára àwọn tó pesẹ síbí ipade náà ní Ìgbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Akọ̀wé tí Ìjọba orílẹ-èdè yìí Boss…