Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ̀ka Òfurufú Tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Wà Ni Ipò Kejì Tó Dára Jùlọ́ Làgbáyé Lẹyìn Àjàkálẹ̀ Àrùn…

Nàìjíríà wà ní ipò Kejì lẹyìn Columbia nínù Ìgbìmọ̀ apapọ ọkọ òfurufú àgbáyé lori atunto lẹyìn Covid-19. Mínísítà fún Ọkọ Òfurufú, Alàgbà Hadi Sirika fí ìdí rẹ̀ múlẹ̀ nígbàtí o ń bá àwọn aṣòfin àpapọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọrọ ní Ọjọ́rú,…

Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Etiópíà Ṣé Ìwọ́de, Bú Ẹnu Àtẹ Lù Ìwọ̀-Òòrùn Àgbáyé

Ọpọlọpọ àwọn ìlú àti ìpínlẹ̀ ní Etiopia ní wọ́n tí ṣé ìwọ́de bí wọ́n ṣé lòdì sí Ìwọ̀-òòrùn. Ìwọ́de náà ní a gbàgbọ́ pé ìjọba ìbílẹ̀ ṣé làti ṣé àtìlẹ́yìn fún ìjọba àpapọ̀ lórí bí wọ́n ṣé ń ṣé ikọlù tuntun sí àgbègbè Tigray tí ogún tí ń…
button