Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ Àwọn Aláṣẹ Orílẹ-èdè Nàìjíríà Gbà Ètò Ìṣúná 2023 Tí Ìlé-ìṣẹ́ Ààrẹ Gbekalẹ Wọlé

Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ tí orílẹ-èdè yìí tí fọwọ́sí ìmọràn ìṣúná 2023 láti fí ṣọwọ́ sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àpapọ̀. Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Ààrẹ lórí ìròyìn àti Ìpolongo, Femi Adesina sọ èyí fún àwọn oníròyìn lẹyìn ìpàdé tó wáyé ní Ọjọ́bọ̀ tí Ààrẹ…

Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìrànlọ́wọ́ Tó Ní Idẹna Láti Kúrò Ní Tigray Ethiopia Tí Gbà Òmìnìra

Àwọn òṣìṣẹ́ ìrànlọ́wọ́ UN ní àgbègbè Ethiopia tó ni ìdènà láti jáde ní Tigray nigbati ìjà bẹ sílẹ̀, tí gbà òmìnìra lẹyìn ọsẹ púpọ̀ ní ìpamọ́. Ọkàn nínú àwọn olórí ni UN Martin Griffiths sọ lórí ẹrọ ayélujára rẹ pé “àwọn òṣìṣẹ́ náà ní…

Àwọn Ololufẹ Olùdijé Ààrẹ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC NÍ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ṣé Iwọde Àtìlẹ́yìn Fún

Àìmọye àwọn alatilẹyìn fún olùdijé ipò Ààrẹ Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) Asíwájú Bola Ahmed Tinubu, ṣé ìpolongo ìbó káàkiri ìgboro ìlú Ìbàdàn, olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, fún àwọn olùdijé Ààrẹ Tinubu/Shettima níbí ìdìbò…

Ètò Ń Tẹ̀síwájú Lórí Òṣùwọ̀n Owó Oṣù Tuntun Fún Àwọn Olùkọ́ – NUT

Ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (Nigeria's Union of Teachers NUT) sọ pé iṣẹ́ ń lọ lọ́wọ́ lórí òṣùwọ̀n owó oṣù tuntun fún àwọn olùkọ́. Akọ̀wé Àgbà tí ẹgbẹ́ náà, Dókítà Mike Ike-Ene, sọ èyí di mímọ̀ ní Abùjá l'akoko tó ń bá àwọn…

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Yóò Gbé Ìwé-Ètò Ìṣúná Ọdún 2023 Lọsí Ìlé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àpapọ̀

Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò gbé àwọn àbá ètò ìsúná ọdún 2023 wá ní ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ keje, oṣù kẹwàá ọdún 2022 sí ìpàdé ìpejọ àpapọ̀ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Nàìjíríà, ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè. Ààrẹ ilẹ̀ ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, Ahmad Lawan sọ…

Ààrẹ Buhari Lerí Láti Jẹ́ Kí Ìjọba Tiwá-ń-tiwá Túbọ̀ Fí Ẹsẹ Múlẹ̀ Sí Ní Ìdìbò 2023

Ààrẹ Muhammadu Buhari sọ pé ètò ìṣàkóso réré nìkan ló lè ṣèrànwọ́ láti mú ìjọba tiwá-ń-tiwá múlẹ̀ ní Nàìjíríà. Nitorinà o tí ṣé ìlérí láti ríí dájú pé àwọn ìdìbò tó tọ, tí àwọn ará ìlú yóò ní igbẹkẹle nínú rẹ̀ ati tí yóò dájú bí…
button