Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ APC Ìpínlẹ̀ Kwara Fọwọ́sí Àwọn Olórí Ẹgbẹ́ Tuntun

Àwọn Olórí ẹgbẹ́ òṣèlú 'All Progressives Congress APC' ti Ìpínlẹ̀ Kwara ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, tún gbá àṣẹ láti tẹ̀síwájú ṣe olórí jákèjádò Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rindínlógún pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ gbogbo ọmọ ẹgbẹ́. ‎ ‎ Ìgbésẹ̀ náà, èyítí o fa àwọn…

Gómìnà Kano Gbóríyìn Fún INEC Àti Àwon Ilé-iṣẹ́ Ààbò Fún Ìdìbò Àlàáfíà

‎Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano, Abba Yusuf, ti yín Ìgbìmọ̀ Elétò Ìdìbò Olómìnira Orílẹ̀-èdè (INEC), àti àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò fún iṣẹ́ àlàáfíà àti ìlànà tí ìdìbò abẹ́lé ní Ìpínlẹ̀ náà. ‎ ‎ Ìyìn Gómìnà náà ní a gbé jáde nínú àtẹ̀jáde kán tí agbẹnusọ…

Mínísítà Fún Iṣẹ́ Nàìjíríà Bú-Ẹnu-Àtẹ-Lú Ìwà Ìbàjẹ́ Ni Òpópónà Èkó Sí Calabar

Mínísítà fún Iṣẹ́ ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Dave Umahi, tí bú-ẹnu-àtẹ-lú àwọn ìwà ìbàjẹ́ àwọn ènìyàn ní òpópónà Èkó sí Calabar, Ó sí kìlọ̀ pé ọwọ́ òfin yóò mú àwọn tó ń hu ìwà ìbàjẹ́ náà. ‎ ‎ Mínísítà ṣe ìkìlọ náà nígbà àyẹwò iṣẹ rẹ̀ ní…

Ààrẹ Tinubu Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Àwọn Olórí Ìbílẹ̀ Àti Ẹ̀sìn Káàkiri Nàìjíríà

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti ké sí àwọn olórí ìbílẹ̀ àti ẹ̀sìn ní gbogbo orílẹ̀-èdè láti ṣètìlẹ́yìn fún àwọn ìsapá ìjọba lójúnà láti ṣàṣeyọrí ìlera gbogbogbò. Ó ní, ipa wọn lórí ìbílẹ̀ jẹ́ pàtàkì sí àwùjọ àti ìṣọ̀kan tó ní ṣe pẹ̀lú gbogbo…

Nàìjíríà Kìlọ̀ Fún Àwọn Ọmọ-ìlú Láti Máa Dá Sí Àwọn Ìjà Ológun Orílẹ̀-èdè Mìíràn

‎Ìjọba Nàìjíríà ti fi àníyàn ńlá hàn lórí àwọn ọ̀ràn tó ń pọ̀ sí i nípa bí àwọn ọmọ-ìlú Nàìjíríà ṣe ń kópa nínú àwọn ìjà ológun olówó-ìlú láti orílẹ̀-èdè mìíràn, ó kìlọ̀ pé irú àwọn ìgbòkègbodò bẹ́ẹ̀ lè fa ewu ńlá sí ẹ̀mí àti pé wọ́n rú…

Nàìjíríà àti UK Ń Mú Ìbáṣepọ̀ Lágbára Síi Kí Ààrẹ Tinubu Tó Bẹ̀rẹ̀ Ìbẹ̀wò

Lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ìpàdé Àṣà Kọkàndínlọ́gbọ̀n ti Àpérò Àwọn Olórí Orílẹ̀-èdè àti Ìjọba ti Àjọ Àwọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà (AU) ní Addis Ababa, Ethiopia, Minisita fún ilẹ̀ Òkèèrè ti Nàìjíríà, Ambassador Yusuf Tuggar, bá Minisita fún Ìdàgbàsókè Àgbáyé…
button