Ilé-iṣẹ́ ìjọba yóò ṣàtúnṣe lórí ìlànà ìwé ìrìnnà Nàìjíríà àti Físà
Ilé-iṣẹ́ ìjọba to n risi ọrọ inu orilẹ-ede ti pinnu lati ṣàtúnṣe lórí ìlànà ìwé ìrìnnà Nàìjíríà àti Físà lati ba ti agbaye ati bi o ṣe n lọ mu, pẹlu iranlọwọ awọn to nii ṣe pataki ni orilẹ-ede.
Igbesẹ yii waye lati…