Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara kí Emir ti ìlú Ilorin kú ọdún méjìdín-lọ́gbọ̀n lórí oyè

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara tí ó tún jẹ́ alága ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà ní Nàìjíríà (NGF), AbdulRahman AbdulRazaq, ti kí Emir ti ìlú Ilọrin, Dokita Ibrahim Sulu-Gambari (CFR), kú àjọ̀dún ọdún kejìdín-lọ́gbọ̀n lórí oyè…

Ilé-ẹjọ́ dá ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ dúró lórí bíbẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì ní ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù…

Ilé ẹjọ́ tó ń rísí ọ̀rọ̀ ilé-iṣẹ́ lórílẹ̀-èdè, ní  Abuja ti dá ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ (NLC), ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ oní kátàkárà (TUC) àti àwọn tí ó tún so mọ́ wọn dúró lórí bíbẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì èyíkééyí tábí ti…

Àbẹ̀wò Igbákejì ààrẹ Shettima sí China ṣe àtúnṣe lórí ọgbọ́n àjọṣepọ̀ Nàìjíríà́ –…

Asojú Nàìjíríà sí China, Jedda Ahmed ti sọ pé àbẹ̀wò tí igbákejì ààrẹ ṣe láìpẹ́ yìí ti tún àjọṣepọ̀ tó wà láàrin orilẹ̀-èdè méjèèjì ṣe. Aṣoju Jedda, ti o ṣe ikede yii nibi ifọrọ wanilẹnuwo pẹlu awọn…

Ìjọba UK Pinnu ìrànlọ́wọ́ fún abala ètò ẹ̀kọ́ ní ìpínlẹ̀ Jigawa

Ìjọba UK ,ti  ìgbìmọ̀ pàtàkì  British ní Abuja ti pinnu láti túnbọ̀ máa ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìjọba ìpínlẹ̀ Jigawa, bí ó ṣe ṣe ìjùmọ̀sọ̀rọ̀ lórí ìṣàtúnṣe ètò ẹ̀kọ́ pẹ̀lú àwọn tó nííṣe. Ile-iṣẹ ijọba to n…

Ẹgbẹ́ Tiv pè fún àlàáfíà láàrin àwọn àgbààgbà tó níkùn sínú síra wọn ní…

Ẹgbẹ́ ìdàgbàsókè Tiv  (TIDA), tó wà lábẹ́ àbojútó àwọn ọmọ bíbí inú Tiv ti ìpínlẹ̀ Nasarawa, ti rọ àwọn ọmọ olókìkí méjì rẹ̀, Aṣòfin Boniface Ifer àti Asọ̀fin Peter Ahemba, láti yanjú aáwọ̀ tó wà láàrin wọn…

Àṣeparí ìdìbò: Àgbékalẹ̀ ẹ̀tọ àwọn akọ̀ròyìn pè fún ìdáábòbò ẹ̀tọ̀ àwọn…

Àgbékalẹ̀ ẹ̀tọ àwọn akọ̀ròyìn (MRA), ti rọ ìjọba Nàìjíríà ní gbogbo ìpele, àwọn Agbófinró àti àwọn ilé-isẹ́ aláàbò láti sa gbogbo ipá wọn láti dáábò bò àwọn akọ̀ròyìn àti àwọn òṣìṣẹ́ oníròyìn…
button