Take a fresh look at your lifestyle.

Arábìnrin àkọ́kọ́ fún àwọn opó àwọn ọmọ ológun tó fẹ̀mí wọn lélẹ̀ fórílẹ̀-èdè lẹ́bùn

Arábìnrin àkọ́kọ́ Nàìjíríà, Sẹnetọ Olurẹmi Tinubu ti fún àwọn opó àti ọmọ àwọn ọmọ ológun tó fẹ̀mí wọn lélẹ̀ fórílẹ̀-èdè lẹ́bùn owo, ní gbọ̀ngàn àwọn ọmọ ológun, ní ibùdó wọn, ní Lungi, Abuja, nípasẹ̀ iṣẹ́…

Àwọn aṣòfin gbóríyìn fún ẹgbẹ́ òsìṣẹ́ bí wọ́n ṣe fòpin sí ìyanṣẹ́lódì

Ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú ti gbóríyìn fún ìgbésẹ̀ tí ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ gbé láti fòpin sí ìyanṣẹ́lódì tí wọ́n rawọ́ lé láti ọjọ́ méjì sẹ́yìn jákèjádò orílẹ̀-èdè. Ninu alaye kan ti alaga igbimọ awọn oṣiṣẹ ati…

Ìjọba Nàìjíríà ṣèpàdé pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ tí ń yanṣẹ́lódì

Ìjọba àpapọ̀ ti ṣèpàdé pẹ̀lú àdari awọn òṣìṣẹ́ NLC, àti ẹgbẹ́ àwọn oní kátàkárà TUC, ní Ọjọ́ọ́rú, láti yanjú ìyanṣẹ́lódì tó ń lọ lọ́wọ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè, tí àwọn méjèèjì kéde. Ipade eyi ti o waye…

Guinea-Bissau ní àádọ́ta ọdún: Ààrẹ Tinubu darapọ̀ láti ṣàjọyọ̀ ayẹyẹ ọdún

Ààrẹ Nàìjíríà Bọla Ahmed Tinubu ti gúnlẹ̀ sí Guinea-Bissau láti kópa nínú ayẹyẹ àyájọ́ àádọ́ta ọdún òmìnira àti ayẹyẹ àyájọ ológun. Gẹgẹ bi alaye lati ọdọ agbenusọ aarẹ, Ajuri Ngelale, adari Naijiria yoo darapọ mọ…

Ìyanṣẹ́lódì jákèjádò orílẹ̀-èdè: Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ Nàìjíríà ti àwọn òṣìṣẹ́, àlejò…

Àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìgbìmọ̀ àti àwọn àlejò tó fẹ́ wọlé tàbí tó fẹ́ jáde nínú ọ́fíísì láàrín ibùdó ilé ìgbìmọ̀ kò ráyè láti agogo mẹ́fà òwúrọ̀, Ọjọ́ọ́rú, ọjọ́ kẹẹ̀dógún, oṣù kọkànlá, 2023. Oni ni…

Ààrẹ orílẹ̀-èdè nígbà kan rí rọ ilé-ìgbìmọ̀ láti máá jẹ́ kí àṣeparí ìdìbò wáyé…

Ààrẹ Naijiria nígbà kan rí, Dokita Goodluck Jonathan ti rọ ilé-ìgbìmọ̀ láti fagi lé àṣeparí ìdìbò ní Naijiria, ti o si ṣapejuwe rẹ gẹgẹ bi ìṣe ti ko dara rara. O pe ipe yii ni ilu rẹ ni Otuoke, ni ijọba ibilẹ Ogbia ti…

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara kí Emir ti ìlú Ilorin kú ọdún méjìdín-lọ́gbọ̀n lórí oyè

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara tí ó tún jẹ́ alága ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà ní Nàìjíríà (NGF), AbdulRahman AbdulRazaq, ti kí Emir ti ìlú Ilọrin, Dokita Ibrahim Sulu-Gambari (CFR), kú àjọ̀dún ọdún kejìdín-lọ́gbọ̀n lórí oyè…
button