Take a fresh look at your lifestyle.

Faransé sọ dókítà Rwanda tẹ́lẹ̀ rí sí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlé-lógún fún pípa ìran kan run

Dókítà Rwandan kan tẹ́lẹ̀ rí ti fi ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlé-lógún gbára láti ilé ẹjọ́ Faransé fún ìlọ́wọ́sí ìparun ìran kan ní ọdún 1994. Sosthene Munyemana jẹbi ipaniyan run, ni Ọjọru, iwa buruku si ọmọniyan ati ikopa…

PDP pe àwọn aṣòfin tó fi ẹgbẹ́ sílẹ̀ lọ sí òmíràn ní Rivers láti fi ipò sílẹ̀

Ẹgbẹ́ alátakò Nàìjíríà, the Peoples Democratic Party, PDP, ti dúró lórí pé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ ìpínlẹ̀ Rivers mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n tó ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ All Progressives Congress, APC gbọ́dọ̀ fi ipò wọn sílẹ̀. Ẹni…

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ké pe ilé iṣé elétò ààbò láti fòpin sí ìpànìyàn ní agbègbè…

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú Nàìjíríà ti rọ olùdámọ̀ràn lórí ètò ààbò lórílẹ̀-èdè (NSA) àti àwọn àgbà elétò ààbò láti gbé ìgbésẹ̀ fún ìfòpinsí ìpànìyàn, bíba dúkìá jẹ ́àti bí àwọn adigunjalè ṣe ń…

Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ rọ VON láti bu iyì kún Nàìjíríà

Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Àlàyé lórílẹ̀-èdè, Mohammed Idris, ti rọ àwọn olùṣàkóso Voice of Nigeria (VON), Asọ̀rọ̀mágbèsì tí ń gbéròyìn torílẹ̀-èdè lọ sí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, láti…

Gómìnà Cross River fún àwọn òṣìṣẹ́ ní ìsinmi ọjọ́ mẹ́rìnlá fún Kérésìmesì

Gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River Gúsù Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Bassey Otu tí buwọlu ìsinmi ọ̀sẹ̀ méjì fún ará ìlú àti àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba tí ń ṣiṣẹ́ fun, fún Kérésìmesì. Alaye kan ti Akọwe agba fun eto iroyin rẹ,…

Mínísítà banújẹ́ lórí ìyàsọ́tọ̀ àwọn ọmọdé abarapá ní ilé-ìwé

Mínísítà fún ètò Ẹ̀kọ́ ní Nàìjíríà, Dokita Yusuf Tanko Sununu, ti pè fún ìdádúró ìyàsọ́tọ̀ àwọn ọmọdé abarapá ní àwọn ilé-ìwé ijọba jákèjádò orílẹ̀-èdè. Mínísítà pe ipe naa nibi ayẹyẹ isami ayajọ…

Amẹ́ríkà fi mẹ́tàlá kún ilé iṣẹ́ China tí wọn kò tíì fìdí òtítọ́ rẹ̀ múlẹ̀

Amẹ́ríkà fi mẹ́tàlá kún ilé iṣẹ́ China tí àwọn òṣìṣẹ́ Amẹ́ríkà kò tíì ṣàyẹ̀wò rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí àkíyèsí ìjọba. Labẹ ilana imuṣẹ lasiko iṣejọba Biden, ti ijọba ko ba fun awọn oṣiṣẹ Amẹrika lanfaani lati ṣe ayẹwo ibudo…

Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ túnbọ̀ fìdí àtìlẹyìn ìjọba múlẹ̀ lórí òmìnira àwọn…

Mínísítà Naijiria fun ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ati Iṣalaye, Mohammed Idris, ti túnbọ̀ fìdí àtìlẹyìn ìjọba múlẹ̀ lórí òmìnira àwọn oníròyìn ni Naijiria. Nigba ti o n sọrọ nibi abẹwo awọn osisẹ lati ile iṣẹ awọn akọroyin…
button