Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu yóò bá orílẹ̀-èdè sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ kìnníí ọdún tuntun

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu yóò bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ jákèjádò lórí afẹ́fẹ́, ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kìnníí ọdún tuntun 2024. Alaye kan lati ọdọ agbẹnusọ aarẹ, Ajuri Ngelale, sọ pe aarẹ yóò bá orílẹ̀-èdè sọ̀rọ̀ ni…

Ìgbìmọ̀ àwọn alákòósó Ilé ìwòsàn Rivers gbóṣùbà fún alága ìjọba ìbílẹ̀

Ìgbìmọ̀ àwọn alákòósó Ilé ìwòsàn Rivers ti gbóṣùbà fún alága ìjọba ìbílẹ̀  Andoni, Erastus Awortu fún ríríi pé iṣẹ́ kò dúró ní ilé ìwòsàn gbogbogbòò tí kìí ṣe tí ìjọba. Ọga agba adari iṣoogun igbimọ,…

Ààrẹ Tinubu ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ ní ọdún mẹ́rìnlé-láàdọ́rin

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), Dókítà Abdullahi Umar Ganduje, fún ọjọ́ ìbí ọdún mẹ́rìnlé-láàdọ́rin rẹ̀, tí ó sì ṣàpèjúwe rẹ̀ bíi tiwantiwa tó…
button