Take a fresh look at your lifestyle.

Eid Al-Maulud: Àpapọ̀ àwọn ọmọ onígbàgbọ́ ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú àwọn mùsùlùmí

Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ onígbàgbò lápapọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,CAN ti bá àwọn àjọ  àpapọ̀  tó ń mójútó ọ̀rán ẹ̀sìn mùsùlùmí (NSCIS ) àti àwọn mùsùlùmí jákèjádò orílẹ̀-èdè ṣàjọyọ̀  ayẹyẹ ọjọ́ ìbí…

Ààrẹ Bùhárí kí Gowon kú oríire ọdún kẹtàdín-láàdọ́rùn ún ọjọ́ ìbí rẹ̀

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti kí ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí,ajagun fẹ̀yìntì Yakubu Gowon ní orúkọ ìjọba àti gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè kú oríire ọjọ́ ìbí ọdún  kẹtàdín-láàdọ́rùn ún rẹ̀.…

À̀àrẹ Bùhárí kí Gómìnà Ikpeazu kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti bá gómìnà Okezie Ikpeazu ti ìpínlẹ̀ Abia yọ̀ lórí ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀,tí ó jẹ́ ọjọ́ kejì-dín-lógún oṣù kẹwàá, ọdún 2021.Gómìnà ọ̀hún pé ọmọ ọdún mẹ́tà-dín-lọ́gọ́ta. Aarẹ darapọ…

Ìṣọ̀kan Ìjọba Nàìjíríà kò ṣí fún Ìdúnàádúrà- Mínísítà

Pẹ̀lú àwọn làásìgbò àti ìgbógun ti  ìwà ọ̀daràn káàkiri orílẹ̀-èdè, ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tún tẹnumọ pé òhun kò ní fọwọ́ hẹ ìṣọ̀kan ìjọba òhun. Minisita Alaye ati Aṣa ti orilẹ -ede, Alhaji Lai…

Ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ epo ilẹ̀ àti gáásì, NUPENG, so ìyanṣẹ́lódì tí ó ń gbèrò kọ́

Ẹgbẹ́ Àwọn òṣìṣẹ́ Epo ilẹ̀  àti  Gáásì, NUPENG, sọ pé ó ti da ìyanṣẹ́lódì   tí ó pinnu fún  iṣẹ́  àwọn awakọ̀ Táńkà epo tí ó yẹ kí ó bẹ̀rẹ̀ láàrin ọ̀gànjọ́ òru ọjọ́ àìkú, ọjọ́ kẹwàá,Oṣù Kẹwàá, Ọdún 2021…

Ọ̀gá àgbà fún àwọn ọmọ ogun bẹ̀rẹ̀ àyẹ̀wò Ìdánilẹ́kọ́ ìdárayá orí pápá

Lẹ́yìn tí wọ́n ti ṣe ìfilọ́lẹ̀  àwọn  Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìdárayá  orí pápá fún àwọn ọmọ ogun mẹ́ta Nàìjíríà ní ọjọ́ àìkú,ọjọ́ kẹrin, Oṣù Kẹwàá ọdún 2021, ní Emene ní ìpínlẹ̀ Enúgu, gúúsù ìlà-oòrùn…
button