Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà : lílo ìmọ̀ èrọ yóò so dídùn fún ìtaláyà ààbò

Mínísítà  Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ọrọ̀ Ajé orí ayélujára, ọ̀jọ̀gbọ́n Isa Pantami ti tẹnumọ́ ìwúlò fún ìgbékalẹ̀ àwọn ètò ìmúlò ààbò pẹ̀lú èrò ìmọ̀-ẹ̀rọ láti kojú àwọn làásìgbò ààbò ní orílẹ̀-èdè.…

Nàìjíríà Le Borí Àwọn Ìpeni níjà Nípasẹ̀ Ìwádìí – Ọ̀gá TETFund

Akòwé Aláse àjọ tó ń mójútó ìnáwó áwọn ilé-ìwé èkọ́ gíga  (TETFund), ọ̀jọ̀gbọ́n Suleiman Bogoro, sọ pé Nàìjíríà le bori àwọn ìtaláyà rẹ̀ nípasẹ̀ Ìwádìí àti Ìdàgbàsókè. Bogoro sọ eyi ni ilu Abuja…

COAS gbóríyìn fún Àwọn ọmọ ogun Fún àìtúrásílẹ̀ àti ìfaradà wọn

Ọ̀gá àgbà  fún àwọn ọmọ ogun, ajagun Faruk Yahaya (COAS), sọ pé òhun  nírètí  pẹ̀lú àìtúrasílẹ̀ àti ìgboyà  àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè (NACA)  àti ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó ìdánilékọ̀ọ́ àwọn ologun,  (NATRAC)…

Ìjàǹbá Ìjì ilẹ̀: Nàìjíríà bá orílẹ̀-èdè Amẹ́ríká kẹ́dùn

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti bá  orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà  àti àwọn ènìyàn rẹ kẹ́dùn  lori ìjì ilẹ̀  tí ó jà káàkiri ní ìpínlẹ̀ mẹ́fà,ní eléyìí tí ó ba ọ̀pọ̀lọpọ̀ dúkìá jẹ́  tí ó sì tún mú ẹ̀mí dání. O sọ pe ohun ba gbogbo awọn…
button