Ìjọba àpapọ̀ fọwọ́sí iye owó tó tó bílíọ́nù méjì ààbọ̀ Náírà fún abala nǹkan…
Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ ti fọwọ́sí iye owó tótó bílíọ́nù méjì àbọ̀ Náírà fún ríra àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn irúgbìn, láti pèsè nǹkan ọ̀gbìn lọ́pọ̀ yanturu ní orílẹ̀-èdè.
Minisita fun eto ọgbin, Mustapha Shehuri…