Take a fresh look at your lifestyle.

Fífa ọwọ́ àdéhùn òfin ìdìbò sẹ́yìn fún dáadáa Nàìjíríà ni – Ààrẹ

Ilé-ìgbìmọ̀ ààrẹ sọ pé  ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí  fawọ́ ìfẹsẹ̀múlẹ̀ Àtúnse ètò Ìdìbò, (Act) 2021 sẹ́yìn fún dáadáa orílẹ̀ -èdè ni. Ninu ifiranṣẹ kan, Oluranlọwọ pataki si Aarẹ lori iroyin ati ipolongo, Farba…

NIDOE yóò Dá ibùjókòó ìdókòwò fún àwọn ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n ń gbé ní òkè…

Ẹgbẹ́ Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà  tó ń gbé lókè  òkun (NIDOE),  ẹ̀ka orílẹ̀-èdè Itali , sọ pé ó ń gbèrò láti kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíónù dọ́là 'Diaspora Village' ní Nàìjíríà gẹ́gẹ́ ,bí ara àwọn…

Ìjàǹbá Iná Àbújá: Mínísítà fún ọmọnìyàn kẹ́dùn pẹ̀lú àwọn olùfaragbá

Mínísítà fún ètò ọmọnìyàn, ètò  àjálù àti ìdàgbàsókè àwùjọ, Sadiya Umar Farouq ti kẹ́dùn lórí ìpàdánù ọjà àti dúkìá tí ó tó bílíọ̀nù owó dọ́là Náírà, nínú ìṣẹ̀lẹ̀ iná tó wáyé ní ilé…
button