Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì ààrẹ kí Aṣiwájú Bọ́lá Tinúubú kú ayẹyẹ ààdọ́rin ọdún

Igbákejì Ààrẹ Yẹmí Ọ̀sínbàjò ti kí Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó nígbàkan rí àti olórí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, Asiwájú Bọ́lá Tinúubú, kú oríire ayẹyẹ ààdọ́rin ọdún. Ọjọgbọn Ọṣinbajo darapọ mọ gbogbo…

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí kí Bọ́lá Ahmed Tinúbú kú àjọ̀dún àádọ́rin ọdún

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ẹgbẹ́, aṣáájú-ọ̀nà àti àwọn olóyè ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) láti bá Bola Ahmed Tinubu tó jẹ́ Aṣiwaju ẹgbẹ́ náà látìgbà tí wọ́n ti dá sílẹ̀ lọ́dún 2013 tó…

Ìkọlù Pápá ọkọ̀ òfurufú Kàdúná:ikọ̀ Àwọn aṣojú bẹ̀rẹ̀ ìwádìí

Aṣojú ikọ̀ Minọ́rítì  ní Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ti pè fún ìwádìí kíkún ní kíákíá sí nǹkan tí ó fa  ìkọlù àti bí àwọn oníjàgídíjàgan ṣe já Pápá ọkọ̀ òfurufú  Kàdúnà gbà ní ọjọ́ àbámẹ́ta. Ikọ naa…
button