Ìṣọ̀kan Ìjọba Nàìjíríà kò ṣí fún Ìdúnàádúrà- Mínísítà
Pẹ̀lú àwọn làásìgbò àti ìgbógun ti ìwà ọ̀daràn káàkiri orílẹ̀-èdè, ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tún tẹnumọ pé òhun kò ní fọwọ́ hẹ ìṣọ̀kan ìjọba òhun.
Minisita Alaye ati Aṣa ti orilẹ -ede, Alhaji Lai…