Take a fresh look at your lifestyle.

Ayẹyẹ EndSARS : Àwọn ikọ̀ ọmọ ogun kò yìnbọn pa àwọn a-fẹ̀hònúhàn ní ibùdó ọkọ̀ Lekki –…

Ijọba orilẹ ede Naijiria ti tun tẹnumọ ọn pe , ikọ ọmọ ogun orile ede Naijiria ti wọn ko lọ lati pese aabo ni ipinlẹ Eko, paapaa julọ ni ibudo ọkọ Lekki ko yinbọn pa ẹnikankan ninu awọn to fẹhonuhan lati gbogun t bi awọn ọlọpaa SARS se n hu…

Eid Al-Maulud: Àpapọ̀ àwọn ọmọ onígbàgbọ́ ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú àwọn mùsùlùmí

Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ onígbàgbò lápapọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,CAN ti bá àwọn àjọ  àpapọ̀  tó ń mójútó ọ̀rán ẹ̀sìn mùsùlùmí (NSCIS ) àti àwọn mùsùlùmí jákèjádò orílẹ̀-èdè ṣàjọyọ̀  ayẹyẹ ọjọ́ ìbí…

Ààrẹ Bùhárí kí Gowon kú oríire ọdún kẹtàdín-láàdọ́rùn ún ọjọ́ ìbí rẹ̀

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti kí ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí,ajagun fẹ̀yìntì Yakubu Gowon ní orúkọ ìjọba àti gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè kú oríire ọjọ́ ìbí ọdún  kẹtàdín-láàdọ́rùn ún rẹ̀.…

À̀àrẹ Bùhárí kí Gómìnà Ikpeazu kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti bá gómìnà Okezie Ikpeazu ti ìpínlẹ̀ Abia yọ̀ lórí ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀,tí ó jẹ́ ọjọ́ kejì-dín-lógún oṣù kẹwàá, ọdún 2021.Gómìnà ọ̀hún pé ọmọ ọdún mẹ́tà-dín-lọ́gọ́ta. Aarẹ darapọ…
button