Ẹ pèsè ìdábòbò tó péye ní gbogbo agbègbè yín o
Mínísítà fún ètò-ẹ̀kọ́, Àdàmú Àdàmú ti pàsẹ fún àwọn ọ̀gá àgbà ilé ìwé gíga àpapọ̀ jákèjádò orílẹ̀-èdè yìí láti bá àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò tó wà lágbègbè wọn fọwọ́ sowọ́pọ̀ láti le dènà ìkọlù…