2027: Míní́sítà fún Iṣẹ́ buwọ́lu èròńgbà Gómìnà Nwifuru lóríi sáà kejì
Gómìnà tó ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò ní ìpínlẹ̀ Ebonyi tí ó jẹ́ Mínísítà fún ètò ìṣẹ́ lọ́wọ́ báyìí, Sẹ́nétọ̀ David Umahi ti sọ pé òun ti tẹ́wọ́gba àtúnyàn Gómìnà Francis Nwifuru fún sáà kejì lórí oyè nínú ìbò…