Ààrẹ Buhari Ṣ’ọfọ Olórí Àwọn Chinese Nígbà-Kán-Rí
Ààrẹ Muhammadu Buhari sọ pé ikú Olórí Òṣèlú Communist nígbà kàn rí, Jiang Zemin ọmọ ọdún mẹ́rindínlọgọ́rùn-ún "jẹ òfo ńlá aláìlẹ́gbẹ fún Orilẹ-ede náà"
Buhari ni "Akọni yìí ni ó rán China lọ́wọ́ láti darapọ…