Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ ECOWAS Ti Ké Sí Orílẹ̀-èdè Senegal Láti Mú Ọjọ́ Mìíràn Fún Ìdìbò Ààrẹ Tí Wọ́n…

Àjọ tó ń rísí ọrọ̀ ajé àwọn ipinlẹ Iwọ-oorun Afirika (ECOWAS) ti rọ àwọn alaṣẹ Orílẹ̀-èdè Senegal lati jára mọ mímú ọjọ tun tun fún idibo aarẹ Orílẹ̀-èdè náà tí wọn sun síwájú Agbegbe tó sọrọ yii ninu ọrọ kan ti…

Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìjàmbá Ìbúgbàmù: Ọwa Obòkun Ilẹ Ìjèṣà Ṣe Àbẹ̀wò Ìbánikẹ́dùn Sí Olúbàdàn Ilẹ̀ Ìbàdàn

Olúbàdàn ilẹ Ìbàdàn, Ọba Lekan Balogun Allí Okunmade II ti sọ di mímọ̀ pé ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ìbúgbàmù to wáyé ni agbègbè Bódìjà ni ìlú Ìbàdàn yẹ kó je ẹkọ fún ẹnikọọkan láti jí giri sí ààbò ara wọn àti fún àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò lati wa loju iṣẹ́.…

Ilé Ẹjọ́ Rán Àwọn Oníjibiti Orí Ẹ̀rọ Ayélujára Mẹ́tàdínlógun (17) Lọ Ọgbà Ẹ̀wọn Ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Àti…

Ile ẹjọ́ ti ran àwọn onijibiti orí ẹrọ ayélujára metadinlogun (17) tí ọwọ́ sìnkún Àjọ EFCC gba mú lọ ọgbà ẹwọn ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti Ìpínlẹ̀ Ogun.  Àwọn metadinlogun náà ti wọn rojọ́ níwájú Onídàájọ́ Olusola Adetujoye to jókòó ní ilé ẹjọ…

Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìbúgbàmù: Peter Obi Ṣe Àbẹ̀wò Si Gómìnà Seyi Makinde

Ẹni tó jẹ́ Oludije du ipò Ààrẹ labẹ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú Labour (LP) nínú ètò ìdìbò gbogboògbò to kọjá, Peter Òbí ló ṣe àbẹ̀wò láti kẹ́dùn pẹ̀lú Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde látàrí ìṣẹ̀lẹ̀ ìbúgbàmù tó wáyé ni ọjọ́ Kẹrìndínlógún oṣù yìí,…

Ẹ̀pa Ò Gbóró Fún Orílẹ̀-èdè Cameroon, Bí Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Ṣe Lé Wọn Padà Lọ Sí Ìlú Wọn Pẹ̀lú…

Super Eagles àti Àwọn agbabọọlu Cameroon tí a tun mọ wọn sí Indomitable Lion bẹrẹ ere bọọlu ti ipele ofìdí rẹmi, o gba ilé rẹ̀ẹ lọ ti ẹlẹyinbo n pe n Knock Out ní dede aago mẹsan-an alẹ́ Ajayi ọmọ ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles lo…
button